The Sixteen Principles of Yoruba Life, Belief and Worship
The Odu Ifa Ika Ofun gave the insight into how Olodumare instructed Orunmila on these principles.
It goes thus,
Ikafun Ikaofun adifa fun awon agbagba merindilogun
Ti nti ode orun bo wa si ile aye
Won rele ife won lo re toro ogbo
Won rele ife won lo re toro ato
Won ni nje awon le gbo bi, nje awon le to be?
Won bi Olodumare ninu ifa ti won da
Won ni won agbo, won ni won atoo
Ti nwon bale pa ikolo mo
Ekini - Won ni kiwon mafi esuru pe esuru
Ekeji - Won ni kinwon mafi esuru pe esuru
Eketa - Won ni kiwon mafi odide pe oode
Ekerin - Won ni kiwon mafi ewe iroko pe ewe oriro
Ekarun - Won ni kiwon mafi aiwe bawon de odo
Ekefa - Won ni kiwon mafi aini oko baweon ke hain hain
Ekeje - Won ni kiwon magba ona eburu wole akala
Ekejo - Won ni kiwon mafi iko odide nudi
Ekesan - Won ni kiwon ma su sepo
Ekewa - Won ni kiwon ma to safo
Ekankanla - Won ni kiwon ma gba opa lowo afoju
Ekejila - Won ni kiwon ma gba opa lowo ogbo
Eketala - Won ni kiwon ma gba obirin ogboni
Ekerinla - Won ni kiwon ma gba obirin ore
Ekarundinlogun - Won ni kiwon ma soro imule leyin
Ekerindinlogun - Won ni kiwon won san bante awo
Won dele aye tan
Ohun ti won ni kiwon mon se niwon dawole
Won wa bere si ku
Owa ku Orunmila nikan to pa ikilo mo
Won wa ni Orunmila ni o npa won
Nje ati dagba mi odowo mi
Ati dagba re odowo re
Nitori agba kii sofun ni tele ki oto kan ni.